HYMN 417

C.M.S 530 C.H. t. H.C 311 C. M 
(FE 440)
“We mi nu kuro ninu ese mi"
- PS.51:2



1.  OLUWA mo de’bi te Re 

     Nibiti anu po

     Mo fe dariji ese mi

     K'o mu okan mi da.


2.  Oluwa, ko ye k’emi so 

     Ohun ti mba bere

     O ti mo k’emi to bere 

     Ohun ti emi fe.


3.  Oluwa mo toro anu 

     Eyiyi l’opin na

     Oluwa, anu l’o ye mi 

     Je ki anu Re wa.  Amin

English »

Update Hymn