(FE 439) C.M.S 531 C.H. t.H.C 145 7s "‘Enyin o si saferi mi, e o si ri mi, ti e ba fi gbogbo okan nyin wa mi” - Jer. 29:13 1. OLUWA, awa’do Re L’ese Re l’a kunle si A! ma kegan ebe wa Ao wa lasan bi! 2. L’ ona to O yan fun wa L’a nwa O lowolowo Oluwa a ki o lo Titi ‘Wo o bukun wa. 3. Ranse lat’oro Re wa Ti O fi ayo‐fun wa Je ki emi Re ko fun Okan wa ni igbala. 4. Jek’a wa, k’a si ri O Ni Olorun Olore W’alasian, da ‘gbekun si, Ki gbogbo wa yo si O. Amin