HYMN 406

t.Y.M.H.B.813 (FE 429) 
"Bo sarin keke abe Kerubu" - Eze.10:2



1.  EGBE kerubu ti ye

     So fun mi lekan si

     Jesu Kristi l’Oba Ogo 

     Olugbala l’Oba lye 

     Egbe kerubu l’Egbe lye 

     Egbe Kerubu ti ye.

Egbe:  Iyanu, Iyanu, Iyanu 

           Egbe Kerubu ti ye.


2.  Egbe Serafu ti ye

     E f’ogo fun baba

     T’o mu wa ri ojo oni 

     Fi ola fun Baba loke 

     Egbe Serafu l’Egbe lye 

     Egbe Serafu ti ye.

Egbe:  Iyanu, Iyanu, Iyanu

           Egbe Serafu ti ye.


3.  Egbe kerubu ti ye

     E so fun mi ki ngbo 

     Jesu Kristi Olusegun 

     Olusegun l'Oba lye 

     Egbe kerubu I’Egbe lye 

     Egbe Kerubu ti ye. 

Egbe:  Iyanu, Iyanu, Iyanu

           Egbe Kerubu ti ye.


4.  Egbe Serafu ti ye

     T’o mo ti Krist’ nikan 

     Jesu t'o wa niwaju wa 

     Olugbala, Balogun wa 

     Egbe Serafu l‘Egbe lye 

     Egbe Serafu ti ye. 

Egbe:  Iyanu, Iyanu, Iyanu

           Egbe Serafu ti ye.


5.  Egbe kerubu ti ye

     Oba lyanu ni;

     Jesu Kristi, Balogun wa,

     Obangiji l’Oba iye 

     Egbe kerubu l’Egbe lye. 

Egbe:  Iyanu, Iyanu, Iyanu

            Egbe Kerubu ti ye.


6.  Egbe Serafu ti ye

     Egbe Iyanu ni 

     “Olubukun I’Enit‘ o mbo 

     Li oruko Oluwa wa

     Ogo ni fun Baba loke 

     Ogo fun Metalokan. 

Egbe:  Iyanu, Iyanu, Iyanu

           Egbe Serafu ti ye.  Amin

English »

Update Hymn