O.t.H. 229 C.M. (FE 428) "Mo ri oro Re mo si je won " - Jer. 15:16 1. BIBELI iwe aiyeraiye Tani le r’idi re? Tani Ie so idide re? Tani le m'opin re? 2. Asiri Olodumare Iko Oba orun Ida t’o pa oro iku Aworan Olorun. 3. Okan ni O larin opo Iwe aiye ‘gbani lwo l‘o s’ona igbala Di mimo f’araiye. 4. Isura ti Metalokan Oba nla t’o gunwa Jo, tumo ara Re fun mi Ki m'ye siyemeji. 5. Ki m’si o p pelu adura Ki ‘m’k‘ eko ninu re Iwo lwe Aiyeraiye, F’ife Jesu han mi. Amin