H.C 133 C.M. (FE 427) “Oluwa ise Re ti pio to!" - Ps. 104:24 1. IWE kan wa ti kika re Ko soro fun enia Ogbon ti awon t’o ka nfe Ni okan ti o mo. 2. lse gbogbo t’Olorun se L'oke n’ile, n'nu wa Nwon j’okan ninu iwe na Lati f’Olorun han. 3. Imole osupa l’oke Lat’ odo orun ni Be l’ogo Ijo Olorun T’odo Olorun wa. 4. lwo ti O jeki a ri Ohun t‘o dara yi Fun wa l‘okan lati wa O K'a ri O nibi gbogbo. Amin