C.M (FE 424) "Emi o tu Emi mi jade si ara enia gbogbo" - Joeli 2:28 1. EMI Mimo, mi s'okan wa, K'a mo agbara Re Orisun emi ‘sotele T‘imole at'ife. 2. Emi Mimo, l'agbara Re L’awon woli sise lwo l’o nfi oto han wa Ninu iwe mimo. 3. Adaba orun, na ‘ye Re Bo okun eda wa Jeki mole Re tan sori Emi aisoto wa. 4. A o mo Olorun daju B’lwo ba mbe n‘nu wa A o mo ‘jinle ife mimo Pelu awon Tire. Amin