(FE 423) Kemble’s Psl 46 t.H.C 342. L.M “Olorun li abo wa ati agbara” - Ps 46:1 1. OLORUN l’abo eni Re Nigba iji iponju de K‘a wa to se aroye wa A! sa wo t’on t’iranwo Re. 2. B’agbami riru mbu soke Okan wa mbe l’alafia Nigb’ orile at’etido Ba njaya riru omi na. 3. lwe owo ni, oro re Kawo ibinu fufu wa Oro Re m’alafia wa O f'ilera f’okan are. Amin