(FE 420) 119 2nd Pt t.H.C 400 C.M "Nipa ewo Ii odomokunrin yio fi mu ona Re mo? Nipa ikiyesi gegebi oro re" - Ps. 119:9 1. BAWO ni awon ewe wa Y‘o ti ma sora won? Bikose ‘nipa kiyesi Gegebi oro Re. 2. Gba oro na wo ‘nu okan A tan imole ka Oro na ko ope l‘ogbon At‘imo Olorun. 3. Orun ni, imole wa ni Amona wa l'osan Fitila ti nfonahan wa Ninu ewu oru. 4. Oro Re, oto ni titi Mimo ni gbogbo re Amona wa l’ojo ewe Opa l’ojo ogbo. Amin