HYMN 391

t.H.C 6s8s (FE 414)
"Oluwa Iwo li o ye lati gba ogo, ati
ola ati agbara" - Ifi. 4:11



1.  BABA, Eleda wa,

     Gbo orin iyin wa 

     L'aiye ati l'orun 

     Baba Olubukun 

     lwo l‘ogo ati iyin 

     Ope, ati ola ye fun.


2.  Wo Olorun Omo 

     T’O ku lati gba wa 

     Enit‘O ji dide

     Ti O si goke lo 

     Iwo l'ogo, ati iyin

     Ope, ati ola ye fun.


3.  Si O Emi Mimo 

     Ni a korin iyin 

     Iwo t’o f’imole 

     lye si okan wa

     Iwo l’ogo, ati iyin 

     Ope, ati ola ye fun.


4.  Mimo, Mimo, Mimo 

     N‘iyin Metalokan 

     L’aiye ati l’orun

     L'a o ma korin pe

     lwo l’ogo, ati iyin 

     Ope, ati ola ye fun.  Amin

English »

Update Hymn