O. t. H.C 97 7s (FE 413) “Ogo ni fun Olorun li oke orun" - Luku 2:14 1. E fi ogo fun baba Nipa Eniti a wa O ngbo adura wa O nf'eti si orin won. 2. E fi ego fun Omo Kristi, ‘Wo ni Oba wa E wa e korin s‘oke S'Odaguntan elese. 3. Ogo fun Emi Mimo Bi ojo Pentikosti Ru aiya awon ewe F’orin mimo s'ete won. 4. Ogo ni l‘oke orun Fun Eni Metalokan Nitori ihin rere Ati ife Olorun. Amin