H.C 250 t.H.C 16 L.M (FE 404) "Nitori aiye yio kun fun imo Oluwa bi omi ti bo okiun“ - Isa. 11:9 1. EMI anu, oto, ife Ran aghara Re t‘oke wa Mu iyanu ojo oni De opin akoko gbogbo. 2. Ki gbogbo orile ede Ko orin ogo Olorun Ki a si ko gbogbo aiye N'ise Olurapada wa. 3. Olutunu at'Amona Joha ijo enia Re K'araiye mo ibukun Re Emi anu, oto, ife. Amin