t.H.C 254 L.M (FE 402) "Ko mi ni wa, ati imo rere" - Ps. 119:66 1. ADABA orun sokale Gbe wa lo l’apa iye Re Ki o si gbe a wa ga soke Ju gbogbo ohun aiye lo. 2. Awa iba le ri ite Olodumare Baba wa Olugbala joko nibe O gunwa l’awo bi tiwa. 3. Egbe mimo duro yi ka lte Agbara wole fun Olorun han ninu ara O si tan ogo yi won ka. 4. Oluwa, akoko wo ni Emi o de bugbe won wole T'emi o ma ba won wole Ki nma sin O, ki nma korin? Amin