C.M.S 274. o.t.H.C 224, 7s (FE 401) "On o si fun nyin Ii Olutunu miran ki o ma banyin gbe titi Iai" - John 14:16 1. EMl Mimo sokale Ba wa gbe ni aiye yi Fi ohun orun han ni Si ba ni sin Olorun. 2. Ese wa ni okan wa Ti a ko le fi sile Agbara wa ko to se Bi “Wo ko ba pelu wa". 3. Awa nfe k’ese parun L’okan ati l'ara wa Wa, Emi Mimo, jo wa Ko we gbogbo ese nu. 4. Olorun, 'Wo l'awa nfe Fi Emi Re na fun wa K'a le pa ofin Re mo K’a si rin ni one Re. Amin