C.M.S 273 H.C 595 (FE 400) "O mi i won, O ni e gba Emi Mimo” - Job. 20:22 Tune: Bi mo ti ri 1. WA mi si wa, Emi Mimo Tan ‘na orun si okan wa Emi af’ororo yan ‘ni Ti f’emi meje re funni. 2. lse nla Re at‘oke wa N‘itunu, iye, ina ife F‘imole Re igbagbogbo Le okunkun okan wa lo. 3. F'ororo ore-ofe Re Pa oju eri wa ko dan L‘ota jina s'ibugbe wa lre n’igbe ‘biti ‘Wo nso. 4. Ko wa k'a mo Baba, Omo Pelu Re l’okansoso Titi aiye ainipekun Ni k‘eyi ma je orin wa. Amin