HYMN 375

t.H.C 255 C.M 
"Okan mi le mo erupe so mi di aye
gege bi oro re" - Ps. 119:25



1.  EMI mimo, ‘daba orun 

     Wa li agbara Re

     K’o da ina ife mimo 

     Ni okan tutu wa.


2.  Wo b' a ti nrapala nihin 

     T'a fe ohun asan 

     Okan wa ko le fo k‘o lo 

     K’o de ‘bayo titi.


3.  Oluwa, ao ha wa titi 

     Ni kiku osi yi?

     lfe wa tutu be si O 

     Tire tobi si wa.


4.  Emi Mimo ‘daba orun 

     Wa ni agbara Re

     Wa dana ‘fe Olugbala 

     Tiwa o si gbina.  Amin

English »

Update Hymn