C.M.S. 254 8s. 8s. 6s (FE 392) “Awa nyo ni ireti Ogo Olorun" - Rom. 5:2 1. LEHIN aiye buburu yi Aiye ekun on osi yi Ibi rere kan wa Ayipada ko si nibe Ko s’oru af'osan titi Wi mi, ‘wo o wa nibe? 2. “Lekun ogo re ti m’ese" Ohun eri ko le we ‘be Lati b‘ewu re je L’ebute daradara ni, A ko ni gburo egun mo Wi mi, ‘wo o wa nibe? 3. Tani o de ‘be? Onirele To f'iberu sin Oluwa T'won ko nani aiye Awon t'a f'Emi Mimo to Awon t‘o nrin l’ona toro Awon ni o wa nibe? Amin