HYMN 369

(FE 391) C.M.S 251 H.C L.M
"Baba, emi fe ki awon ti lwo fi fun
mi ki o wa peIu mi nibiti emi gbe 
wa” - Job. 17:24


1.  JE ki m'nipo mi lodo Re 

     Jesu, lwo isimi mi

     ‘Gbana l‘okan y’o simi

      Y'o si ri ekun ‘bukun gba.


2.  Je ki m’ n'ipo mi lodo re 

     K’emi ko le ri ogo Re 

     ‘Gbana ni okan etan mi 

     Yio ri eni f'ara le.


3.  Je ki m’ n’ipo mi lodo Re 

     Nibi awon mimo nyin O 

     ‘Gbana ni okan ese mi

     Y’o dekun ese ni dida.


4.  Je ki m'n’ipo mi lodo Re 

     Nibi a ki yipo pada

     Nib’a ko npe, o digbose 

     Titi aiye, titi aiye.  Amin

English »

Update Hymn