HYMN 368

H.C 239 C.M (FE 390)
"O si fi ilu ni han mi, Jerusalem
Mimo" - lfihan 21:10



1.  JERUSALEMU ibi ayo

     T’o se owon fun mi 

     ‘Gbawo n'ise mi o pari 

     L'ayo l'alafia.


2.  Gbawo ni oju mi y‘o ri 

     Enu bode pearl Re? 

     Odi re t‘o le fun ‘gbala 

     Ita wura didan.


3.  Gbawo, ilu Olorun mi 

     L’emi o d‘afin Re? 

     Nibiti Ijo ki ‘tuka 

     N‘ib’ayo ailopin.


4.  Ese t'emi o ko iya 

     lku at'iponju

     Mo nwo ile rere Kenaan 

     Ile ‘mole titi.


5.  Aposteli, Martyr, Woli 

     Nwon y’Olugbala ka 

     Awa tikara wa, fere 

     Dapo mo ogun na.


6.  Jerusalem ilu ayo 

     Okan mi nfa si O

     ‘Gbati mo ba ri ayo re 

     lse mi y’o pari.  Amin

English »

Update Hymn