(FE 386) C.M.S 414 S.M H.C 410 S.M "Awon eni, nipa igbagbo ati suru ti o jogun ilerli wonni" - Heb. 6:12 1. F’AWON enia Re, T'o ti fi aiye sile Awon to mo O, t’ o sin O, Gba orin iyin wa. 2. F’awon enia Re Gba ohun ope wa Awon t’o fi O s’esan won Nwon ku n‘gbagbo Re! 3. Ni gbogbo aiye won ‘Won ni nwon nwo l'oju Emi Mimo Re l’onko won Lati s‘ohun gbogbo. 4. Fun eyi, Oluwa, A nyin oruko Re Je k‘a ma tele iwa won Ki a le ku bi won. Amin