CM (FE 384) 1. E GBO b‘awon Angeli ti Nfi Ogo f'Olorun Ati awon Olus‘Agutan Nfi ‘yin fun U, 2. Gbogbo ogun orun pelu Agba mejila Kerubu pelu Serafu Nfi ‘yin fun U. 3. Oke meje at'egbaji Awon Agba woli Awon t’o nfe l’Olugbala Nf ‘yin fun U. 4. Gbogbo’Ogun orun, e ho ye Aiye gbo iro na, Imisi Emi ba le wa Awa nyin I. 5. N’torina awa Kerubu Ati Serafu Ninu aginju aiye yi Nyin Baba. 6. Ogo fun Baba Olore Ogo f’Omo Re Ogo ni fun Emi Mimo Loke Orun. Amin