HYMN 361

H.C 244 6s 4s (FE 383)
"O ti pese ilu nla kan sile fun won"
- Heb. 11:16



1.  JERUSALEM t'orun 

     Orin mi, ilu mi 

     Ile mi bi mba ku 

     Ekun ibukun mi: 

Egbe:  Ibi ayo! 

            Nigbawo ni 

            Ngo r'oju re 

            Olorun mi?


2.  Odi re, ilu mi

     L'a fi pearl se l’oso 

     ‘Lekun re ndan fun ‘yin 

     Wura ni ita re!

Egbe:  Ibi ayo!...

3.  Orun ki ran nibe 

     Beni ko s'osupa

     A ko wa iwonyi 

     Kristi n‘imole ibe.

Egbe:  Ibi ayo!...


4.  Nibe ni mo le ri 

     Awon Aposteli 

     At‘awon akorin

     Ti nlu harpu wura.

Egbe:  Ibi ayo!...


5.  Ni agbala wonni

     Ni awon Martyr wa 

     Nwon wo aso ala 

     Ogo bo ogbe won. 

Egbe:  Ibi ayo!...


6.  T'emi yi sa su mi

     Ti mo ngb'ago kedar! 

     Ko si ‘ru yi loke

     Nibe ni mo fe lo.

Egbe:  Ibi ayo! 

            Nigbawo ni 

            Ngo r'oju re 

            Olorun mi?  Amin

English »

Update Hymn