(FE 53) C.M.S. 32, K. 125, t.H.C 332 C.M. "Nibe li alare wa ninu isimi" - Job 3:17 1. NlGBAWO Olugbala mi, L'emi o ri O je? N'isimi t'o ni ibukun, Laisi ‘boju larin. 2. Ran mi lowo n‘irinkiri L’aiye aniyan yi; Se mi ki nfi ‘fe gbadura, Si gha adura mi. 3. Da mi si, Baba, da mi si Mo f’ara mi fun O Gba ohun gbogbo ti mo ni, Si f‘ara Re fun mi. 4. Emi re, Baba, fifun mi, K‘o le ma pelu mi, K'o se imole ese mi, S'isimi ailopin. Amin