HYMN 351
(FE 374) C.M.S 257 H.C 423
t. A. &. M. 438 C.M.
"Mo si ri awon oku kekeke ati nla
nwon duro niwaju Olorun” - Ifi. 20:12
1. OKE kan mbe t’o ndan t’o ga
Nibi t’a m’Olorun
O wa l‘okere ni orun
Ite Olorun ni.
2. Tal’awon t’o sunmo ibe
Lati wo ite Re?
Egbarun ‘won t’o wa nibe
Omode bi awa.
3. Olugbala w’ese won nu
O so won di mimo
Nwon f’oro Re, nwon f’ojo Re,
Nwon fe, nwon si ri i.
4. Labe opo oko tutu
La’ara won simi si
Nwon ri igbala okan won he
Laiya Olugbala.
5. K’awa k’o rin bi nwon ti nrin
lpa t’o lo s' orun
Wa idariji Olorun
To ti dariji won.
6. Jesu ngbo irele ekun
T‘o mu okan d’otun
Lori oke t’o dan, t’o ga
L’ awa o ma wo, O. Amin
English »Update Hymn