C.M.S. 29 o.t. H.C 17, L.M (FE 52) “Omo Enia li Oluwa ojo isinmi" - Matt 12:8 1. OLUWA ojo isimi, Gbo tiwa, pelu wa loni Awa pade fun adura A fe gb’oro T’o fi fun wa. 2. Isimi t’aiye yi rorun Sugbon isimi t’orun dun Lala okan wa fe ‘jo na T'a o simi lailese da. 3. Ko s’ija, ko si ‘dagiri Ko s’aniyan bi t’aiye yi T‘y’o dapo mo ikorin wa, T’o nt’ete aiku jade wa. 4. Bebe, ojo t’a ti nreti Afemoju re l’a fe ri A fe yo Iona ise yi, K’a sun n’iku, k’a ji l’ayo. Amin