HYMN 348
H.C 234 D.S.M (FE 371)
"Eni na ti o sokale li o si goke lo
si ibi ti O ga ju gbogbo orun lo"
- Efe. 4:10
1. lwo ti goke lo,
S’ile ayo orun
Lojojumo yite re ka
L‘a ngbo orin iyin
Sugbon awa nduro
Labe eru ese
Jo ran Olutunu Re wa
K’o si mu wa lo ‘le.
2. lwo ti goke lo
Sugbon saju eyi,
O koja ‘rora kikoro
K'o to le de ade
Larin ibanuje
L'a o ma te siwaju
K‘ona wa t'o kun f'omije
To wa si odo Re.
3. Iwo ti goke lo
Iwo o tun pada
Awon egbe mimo l'oke
Ni y’o ba O pada
Nipa agbara Re
K’awa k’a ku n’nu Re
Gbat'a ba ji l’ojo‘dajo
Fi wa si otun Re. Amin
English »Update Hymn