HYMN 341

1.  MO n tesiwaju l’ona naa 

     Mo n g'oke si l’ojoojumo 

     Mo n gbadura bi mo ti n lo 

     Oluwa f'ese mi mu le.

Egbe:  Oluwa joo gbe mi s'oke

            S'ile orun nipa gbagbo

            Bi t'ayo at'ife gbe wa

            Oluwa f'ese mi mu le.


2.  lfe okan mi ko duro

     Laarin yemeji at'eru

     Awon miiran le maa gbe be 

     llepa mi n’ibi giga. 

Egbe:  Oluwa joo gbe mi...


3.  Em'o bori b'idanwo de 

     Okan mi yoo sinmi le O 

     Alaafia kikun si nbe 

     F‘awon t'o ngbe ibi giga.

Egbe:  Oluwa joo gbe mi...


4.  Mo fe de ‘bi giga julo

     B‘o ti wu ki‘ija naa le to 

     No ma ko’rin bi mo ti n lo 

     Oluwa joo mu mi de be. 

Egbe:  Oluwa joo gbe mi...


5.  Oluwa joo s'amona mi 

     Laisi Re n ko ni le de be

     Gba m‘ba si de ilu Orun

     Okan mi yoo f‘ope fun O. 

Egbe:  Oluwa joo gbe mi s'oke

            S'ile orun nipa gbagbo

            Bi t'ayo at'ife gbe wa

            Oluwa f'ese mi mu le.  Amin

English »

Update Hymn