HYMN 339

P.& MP 116 (FE 362)
"Lehin eyi, O fi ara han fun awon 
meji" - Marku 16:12



1.  MO gbo Jesu wipe 

     ‘Agbara re kere, 

     Alare, sora gbadura 

     Pipe re mbe lodo mi.

Egbe:  Jusu san gbogbo 

           Gbese ti mo je

            Ese ti m'abawon wa 

            O fo mi fun bi nso.


2.  Oluwa toto mo mo 

     P’agbara Re nikan 

     Le s’adete di mimo 

     O le m’okan lile ro.

Egbe:  Jusu san gbogbo...


3.  "Gbati ‘pe ‘kehin ba dun 

     T’o npe mi s’odo Re

     Jesu ti san gbogbo re,

     Em’ o ba goke orun.

Egbe:  Jusu san gbogbo 

           Gbese ti mo je

            Ese ti m'abawon wa 

            O fo mi fun bi nso.  Amin

English »

Update Hymn