HYMN 333

(FE 356)
E.O. 158 C.M.S 218 6s. 8s
"Iwo ti di igbekun ni igbekun lo”
 - Ps. 68:18



1.  OORO ayo na de

     Olugbala bori

     O fi ‘boji sile

     Bi Olodurnare.

Egbe:  A d’igbekun ni’gbekun lo, 

           Jesu t'o ku di alaye.


2.  Onigbowo wa ku 

     Tani to fi wa sun? 

     Baba dawa lare 

     Tal' o to da ebi?

Egbe:  A d’igbekun...


3.  Kristi tisan gbese 

     Ise ogo pari

     O ti ran wa lowo 

     O ti ba wa segun.

Egbe:  A d’igbekun ni’gbekun lo, 

           Jesu t'o ku di alaye.  Amin

English »

Update Hymn