HYMN 330

(FE 353)
K. 170 t. H. C 245 S.M
"O jinde nitori idalare wa” - Rom. 4:25



1.  A mu ileri se 

     Ise ‘gbala pari

     Oto at'anu di ore 

     Om’Olorun jinde.


2.  Okan mi yin Jesu

     T'O ru gbogb’ese re

     T’O ku f’ese gbogbo aiye

     O wa, K‘O ma ku mo.


3.  Iku Re ra ‘simi 

     Fun O, l’ O ji dide

     Gbagbo, gba ekun ‘dariji 

     T‘a sa l’ami eje.  Amin

English »

Update Hymn