(FE 352) C.M.S 230 t. H.C 577 6s. 4s “Awon oba aiye kese jo ati awon ijoye ngbimo po si Oluwa" - Ps. 2:2 1. B‘ELESE s'owo po Ti nwon nde s’Oluwa Dimo si Kristi Re Lati gan Oba na B’aiye nsata Pelu Esu, Eke ni nwon Nwon nse lasan. 2. Olugbala joba! Lori oke Sion Ase ti Oluwa Gbe Omo Tire ro Lati ‘boji O ni, k‘ O nde K' O si goke K' O gba ni la. 3. F’eru sin Oluwa Si bowo f 'ase Re F'ayo wa sodo Re F’ iwariri duro E kunle fun K'e teriba So t‘ipa Re Ki omo na. Amin