(FE 351) K. 160 5t.S 747 88.6. Wo ti di igbekun ni igbekun le" - Ps. 68:18 1. JESU t'o ku, k'o gb’aiye la Jinde kuro ninu oku Nipa agbara re A da sile lowo iku O d'igbekun n'igbekun Io O ye, k‘o ma ku mo. 2. Enyin om'OIorun, e wo Olugbala ninu ogo O ti segun iku Ma banuje maberu mo O nlo pese aiye fun nyin Yio mu yin lo ‘Ie. 3. O f’oju anu at'ife Wo awon ti O ra pada Awon ni ayo Re O ri ayo at‘ise won O bebe ki nwon le segun Ki nwon ba joba lai. Amin