(FE 349) K.184. t. H.C 258. S.M "Kristi ti jinde kuro ninu oku" - 1Kor. 15:20 1. OLUWA ji l’oto lhin na ha s‘oto Nwon ti ri p‘Olugbala ku Nwon ri l'aye pelu. 2. Oluwa ji l’oto Oto ko fe ju yi Anu at‘otito pade Ti nwon ti ns‘ota ri. 3. Oluwa ji l‘oto" lse Re l‘ose tan A da ide onigbowo A se apa iku. 4. ‘Oluwa ji l‘oto Boji ko le se mo Awon t‘o ku si ji pelu Nwon ki o si ku mo. Amin