t.H.C 97 7s (FE 344) “E lo so fun nawon omo ehin Re pe O jinde” - Matt. 28:7 1. Lo so fun gbogbo aiye Lo tan ihin ayo yi Eti t'o ba gbo, y’o si, Okan t’o ba gbo, y’o la. 2. Jesu Olugbala wa, T‘a sin, fi ‘boji sile Olorun gba ebo Re, Ebo ese araiye. 3. O ji lati ma ku mo Akobi awon t‘o sun Eniti o ba gba a gbo Yio ye, b'o tile ku. 4. Angeli! eda orun E ba araiye gberin Jesu OIudande ji, Alafia titi lai. Amin