HYMN 319

C.M.S 225 P.M (FE 342)
“E korin titun si Oluwa nitori ti o 
ti se ohun iyanu" - Ps. 98:1



1.  ALLELUYA! Allelua!! Allelua!!! 

     Ija d'opin, ogun si tan 

     Olugbala jagun 'molu 

     Orin ayo la o ma ko 

     Alleluya.


2.  Gbogbo ipa n'iku ti lo 

     Sughon Kristi f'ogun re ka 

     Aiye' E ho iho ayo 

     Alleluya.


3.  Ojo meta na ti koja 

     O jinde kuro n‘nu oku 

     E Fogo fun Olorun wa 

     Alleluya.


4.  O d‘ewon orun apadi 

     O s'ilekun orun sile

     E korin iyin ‘segun Re 

     Alleluya.


5.  Jesu nipa iya t‘o je 

     Gba wa lowo oro iku 

     K'a le ye, k‘a si ma yin O 

     Alleluya.  Amin

English »

Update Hymn