HYMN 313
C.M.S 213. H.C. 201 P.M. 10s
(FE 334)
Tune: Ma gbadura Emi mbebe
ITAN ORI AGBELEBU
“Nwon o ma wo eniti a gun I’ oko."
GETSEMANE
1. N’IWAIYA ‘jakadi/On
nikan nja,
O nfe iranlowo/ sugbon ko ri.
2. B’ opsupa ti nwo/ l’or'oke Olifi.
Adura tani ngoke / loro yi?
3. Eje wo I’ eyiti / nro bi ojo,
Lat’okan Re wa,“E/ ni
‘banuje?
4. lrora aileso/ mbe loju Re,
Ojiya ti mbebe, / tan' lwo?
ONA IKANU (FE 335)
1. GBO b' o ti mba o so/
ro lokan re,
“Omo ti moku fun, / tele mi.
2. “Ki nma m'ago ti / Baba fun mi bi?
‘Gbati mimu re je/ ‘gbala re?”
3. “A lu, a tuto si / a fi sefe,
A na, a si de /l'ade egun.
4. “Mo nlo si golgota / nibe ngo ku,
‘Tor’ife misi O, /Emi ni.”
ORO MEJE LORI AGBELEBU
1. A KAN mo ‘gi esin, / ko ke 'rora.
2. ‘Wo Orun mi, o le / wo okun bi?
'Oro wo l‘o te/ nu Re wa ni?
3. "Baba, dariji won' / l’ adura Re,
Baba si gbo bi / ti ma gbo ri.
4. Gbo bi ole ni ti/ ntoro anu,
On se ‘leri Pa / radise fun.
5. lbatan at‘ Ore / rogba yika,
Maria on Magdalen / r'opin re.
6. Meji ninu won di / tiyatomo,
Okan t' oro Re ; ti so d‘ okan.
7. Okunkun bo ile / osan d' oru,
lseju koja b’ / odun pipo.
8. Gbo 'gbe ‘rora lati / nu okun na,
"Baba ‘Wo ko mi/ sile, ese?
9. A! ikosile nla! / iku egun,
Igbe kil’ eyi, / “Ongbe ngbe mi."
10. Gbo. “O ti pari” / ijakadi pin,
lku at‘ ipoku / a se won.
11. “Baba, gba emi mi“ / l‘o wi kehin:
Krist' Oluwa iye / O si ku. Amin
IKESI (FE 336)
1. OMO 'rora mi ti / mof' eje ra,
Mo gba o low’ esu / f’ Olorun.
2. "Wa, alare, wa f‘ ori / l’aiya mi,
Sa pamo so do mi, k' o simi.
3. ‘Wa s'odo Baba mi / wa laiberu,
Alagbawi re, / wa nitosi.
4. “Wa mu ninu ore-ofe Emi;
Emi ni ini re / “Wo t‘ emi. Amin
English »Update Hymn