1. OLUWA mi ha ta eje Re sile, O si ku? O wa f’ori ogo Re ni Sile fun ‘ru emi? Egbe: Nibi agbelebu ni mo ko r’imole Nibe I’eru okan mi si fo lo (si fo Io) Nibe nipa igbagbo mo riran N'sinyi mo wa I 'alaafia titi. 2. Nje n’tori ‘se ‘bi mi l’O se Kerora lor’igi'? Oore-ofe iyanu ni At‘ife ailegbe! 3. OOrun wo s’inu okunkun O b’ogo Re mole ‘Gba ti Kristi, Eleda ku Fun ese eniyan. 4. Sugbon omije ko le san Gbese ‘f'e ti mo je Oluwa, mo f‘ara mi ‘le Fun ife Re nikan. Amin