HYMN 306

C.M.S. 201 H.C. 483 C.M.
"Ni kaifari l a kon A mo 'gi"
- Luku 23:33



1.  OKE Kan mbe jina rere,

     Lehin odi ilu,

     Nibit' a kan Oluwa mo,

     Eniti' O ku fun wa.


2.  A ko lee mo, a ko le so,

     B'irora Re tito;

     Sugbon a mo pe n' tori wa,

     L'O se jiya nibe.


3.  O ku kale huwa rere,

     K' a le ri 'dariji;

     K' a si le d'orun nikehin

     N' itoye eje Re.


4.  Ko tun s' eni 're miran mo

     To le sanwo ese,

     On lo le silekun orun,

     K' O si gba wa sile.


5.  A! b' ife Re ti sowon to,

     O ye ka feran Re;

     K' a si gbeekele eje Re,

     K' a si se ife Re.  Amin
 

English »

Update Hymn