C.M.S 198. t.H.c. 190 C.M. (FE 345) "Awan dwonyi ni not Odoaguatan Iehin nibikibi ti nre." - lfi. 14:4 1. E JE k’ a to Jesu wa lo, Ni agbala nla ni; Nibiti O nlo gbadura, Nibit' O nlo kanu. 2. K' a wo b’ O ti dojubole T' o nmi imi edun; Eru ese wa l‘ O gberu, Ese gbogbo aiye. 3. Elsese, wo Oluwa re, Eni mimo julo; Nitori re ni Baba ko, Aiye si d‘ ota Re. 4. Iwo O ha wo laironu, Lai k’ ese re silse? Ojo idariji nkoja, Ojo igbala nlo. Amin