C.M.S.2t, S. 634, CM (FE 20) "Emi dubule, mo si su, mo si ji Nitori Oluwa ti mi Iehin" - Ps. 3:5 1. Ninu gbogbo ewu oru, Oluwa l‘o so mi Awa si tun ri' mole yi A tun te ekun ba. 2. Oluwa, pa wa mo l'oni, Fi apa Re so wa; Kiki awon ti ‘Wo pamo L‘o nyo ninu ewu. 3. K’oro wa, ati iwa wa Wipe, Tire l'awa, Tobe t'imole otito Le tan l‘oju aiye. 4. Ma je k’a pada lodo Re, Olugbala owon Titi a o f'oju wa ri, Oju Re li opin. Amin