t.H.C. 233 C.M (FE 313) "lhinrere kristi agbara Olorun nmi si igbala” - Rom. 1:16 1. KRIST t‘agbelebu l’orin wa, ljinle t’awa nso O j’egan loju awon ju Were lowo Griki. 2. Sugbon okan t'Olorun ko F‘ayo gba oro na Nwon ri ogbon, ipa, ife T’o han n’Oluwa won. 3. Adun, oruko Re yiye Mu soji s’okan won Aigbagbo l’ohun t'o ba ni je Si ebi at’iku. 4. Lai j'OIorun t‘o or‘ofe ka Bi owara ojo Lasan l‘Apollos funrugbin Paul si le gbin lasan. Amin