HYMN 291

t.H.C. 68 S.M (FE 312) 
"Ni pepe Re wonni, Oluwa awon
omo Ogun" - Ps. 84:3



1.  SI pepe Oluwa,

     Mo mu ‘banuje wa

     Wo ki o f'anu tewogba, 

     Ohun alaiye yi?


2.  Kristi Odagutan

     Ni igbagbo mi nwo 

     Wo le ko hun alaiye yi? 

     Wo o gba ebo mi.


3.  Gbati Jesu mi ku

      A te ofin l'orun

     Ofin ko ba mi l’eru mo 

     Toripe Jesu ku.  Amin

English »

Update Hymn