C.M.S 193 K. 241 t.H.C 16, L.M (FE 311) 'O ye ki a se ariya, ki a si yo" - Luku 15:22 1. TANl le so t‘ayo ti mbe Ni agbala Paradise Gba t‘amusua ba pada T‘o si di arole ogo? 2. Ni ayo ni Baba fi wo Eso ife Re ailopin L’ayo l'Omo we Ie t’O ri Ere iwaya-ija Re. 3. Tayotayo l’Emi si nwo Okan mimo t'o n so dotun Awon mimo at‘Angel nko Orin Igbala Oba won. Amin