HYMN 283
C.M.S 147 H.C 154 C.M (FE 303)
“Oluwa, ranti mi" - Luku 23:42
1. lWO Iow’enit' ire nsan
Mo gb’okan mi si O
Ni ‘ibanuje at’ise mi,
Oluwa, ranti mi.
2. ‘Gba mo nkerora l'okan mi
T‘ese wo mi l’orun
Dari gbogbo ese ji mi
Ni ife, ranti mi.
3. ‘Gba 'danwo kikan yi mi ka
Ti ibi le mi ba
Oluwa, fun mi l’agbara
Fun rere, ranti mi.
4. Bi ‘tiju at'egan ba de
‘Tiro oruko re
Ngo yo s’egan, ngo gba t'iju,
B‘iwo ba ranti mi.
5. Oluwa, gba iku de
Em’ o sa ku dandan;
K‘eyi j’adura gbehin mi,
Oluwa, ranti mi. Amin
English »Update Hymn