C.M.S 578 K. 616 8s.7s (FE 302) "Ife ni Olorun" - 1 John 4 1. IFE l‘Olorun, anu Re Tan si ona wa gbogbo O fun wa ni alafia Ife ni Olorun wa. 2. Iku ndoro pupopupo Enia si ndibaje Sugbon anu Re wa titi lfe ni Olorun wa. 3. Lakoko t’o dab’o sokun A nri Ore Re daju O tan imole Re fun wa lfe ni Olorun wa. 4. O so 'reti, at‘itunu Mo aniyan aiye wa, Ogo Re ntan nibi gbogbo lfe ni Olorun wa. Amin