HYMN 281

CM.S. 579 C.M (FE 301) 
“Jesu, Baba sanu fun wa:” - Luku 17:13



1.  ESE mi po bi irawo 

     Bi‘yanrin let‘okun

     Sugbon iyonu Olorun 

     O p’apoju be lo.


2.  Manase, Paul, On Magdalen 

     lwo dariji won

     Mo ti ka mo si gbagbo pe

     O ti dariji mi.  Amin

English »

Update Hymn