T.H.C. 150 C.M (FE 300) "Gbo adura mi Oluwa" - Ps.102:1 1. BABA alanu t'o fe wa Mo gb’okan mi si O lpa Re t’o po l'o gba wa; Awa nkorin si O. 2. Tire papa l’awa fe ese Gb’okan wa fun ebo; O da wa, o si tun wa bi A f' ara wa fun O. 3. Emi Mimo, wa sodo mi, F'ife Oluwa han Fun mi k‘emi k’o le ma rin N’ife Oluwa mi. Amin