HYMN 279
C.M. 40 t.H.C 266 L.M (FE 306)
"Bi enyin o ba gbo ohun re, e ma se
aiya yin le" - Ps. 95:7, 8
1. MURA, elese, lati gbon
Ma duro de ojo ola
Niwon b'o ti kegab ogbon
Be l'o si soro lati ti.
2. Murs lati bere anu
Ma duro de ojo ola
Ki igba re ko ma ba tan
Ki ojo ale yi to tan.
3. Mura, elese k’pada
Ma duro de ojo ola
Nitorik’egan ma ba o
K’ojo ola k’o to bere.
4. Mura lati gba ibukun
Ma duro de ojo ola
Ki fitila re ma ba ku
K’ise rere re to bere.
5. Oluwa, y‘elese pada
Ki kuro ninun were re
Ma je k’o tapa s’imo Re
K’o ma f'egbe re se 'lora. Amin
English »Update Hymn