HYMN 278

C.M.S 156 T.H.C 182 C.M (FE 298)
"Pa oju Re mo kuro lara ese mi" 
- Ps. 51:9



1.  RO iponju mi, Oluwa

     Ran iranlowo Re!

     Okan mi daku fun 'gbala

     Ise mi ki o pin?


2.  Mo ri pe o dara fun mi

     Bi Baba mi na mi

     Iya mu mi k ofin Re 

     Ki ngeke mi le O.


3.  Mo mo pe idajo Re to

     Bi o tile muna

     Iponju ti mo f'ori ti

     O ti odo Re wa.


4.  K'emi to m'owo ina Re

     Emi a ma sina

     Sugbon bi mo ti k'oro Re

     Emi ko sako mo.  Amin

English »

Update Hymn