H.C 117 6s (FE 297) “ljoba re de" - Matt. 6:10 1. KRIST’ ki 'joba Re de Ki ase Re bere F’opa-irin Re fo Gbogbo ipa ese. 2. ljoba ife da Ati t'alafia Gba wo ni irira Yio tan bi t'orun? 3. Akoko na ha da T’ote yio pari lka at‘ireje Pelu ifekufe? 4. Oluwa jo, dide Wa n’nu aghara Re Fi ayo fun awa Ti o ns‘aferi Re. 5. Eda ngan oko Re Koko nje agbo Re lwa ‘tiju pupo Nfihan pe ‘fe tutu. 6. Okun bole sibe Ni ile keferi Dide 'Rawo oro Dide, mase wo mo. Amin