C.M.S 148 t.H.C 94 S.M (FE 295) "Wa eni mi" - Isa. 26:20 1. BABA wa orun npe Krist‘ npe wa sodo Re Ore wa pelu won o dun Dapo wa y’o s’owon. 2. Olorun nkanu mi O dar‘ese mi ji Olodumare s’okan mi O f’ogbon to pa mi. 3. Ebun Re ti po to! Ol'opo isura T’a t’owo Olugbala pin Ti a f’eje Re ra! 4. Jesu, Ori ‘ye mi Mo fi ‘bukun fun O Alagbawi lodo Baba Asaju lodo Re. 5. Okan at’ife mi E duro je nihin Titi ‘dapo yio fi kun L'oke orun l’ohun. Amin